# of occurrences |
# of sentences |
Sample sentence |
0 |
2139 |
Aaglacrinus jẹ́ ẹ̀yà crinoidea ní ìhà Cladia tí a kò rí mọ́. |
1 |
2607 |
Ààfin ọba ni ilé ẹjọ́ tó ga jù. |
2 |
1894 |
Ààbò lo ko nǹkan ìlò ọkọ rẹ lo ta ni ọjà Ejigbomekan ní owó pọ́ọ́kú ó ra ounjẹ wọn ṣi tójú àwọn àlejò wọn. |
3 |
1289 |
Aago mẹ́fà sí mẹ́jọ ni ọ̀gá ọlọ́pàá máa ń rí ènìyàn ṣùgbọ́n ó gbà láti rí Akin àti Ilésanmí lẹ́yìn ìgbà tí ó ti rí káàdì Akin. |
4 |
879 |
Aare ile India ni olori orile-ede to je didiboyan latowo igbimo onidiboyan fun igba odun marun kan. |
5 |
465 |
Àáró, ìgbẹ́ ọdún dídẹ, ìsingbà tàbí oko olówó, Gbàmí-o-ràmí àti Èésú tàbí Èsúsú jẹ́ ọ̀nà ìràn-ara-ẹni-lọ́wọ́. |
6 |
326 |
Aare Thabo Mbeki yoo kuro ni ojo kejo osu kejo ni odun 2007,leyin igba na ni o bojuto ipa re gegebi ara egbe awon asofin oduro fun African National Congress. |
7 |
168 |
Abẹ́ igi yíì fẹjú, ó tutu, ó sì gbòòrò tó bẹ́ẹ̀ tí o lè gba èèyàn púpọ̀ láti seré bíì ìjàkadì ayò ọpọ́n abbl. |
8 |
121 |
Adebisi Agboola (ojoibi 11 August, 1964 ni Ogbomosho ) je omo Yoruba ara Amerika onimo mathimatiki to je ojogbon ni Yunifasiti Kalifornia ni Santa Barbara. |
9 |
58 |
Ara ìwàrẹ̀fà mẹfà ni Ọ̀gbọ́ni méjèejì yí wa ni Iléṣà ṣùgbọ́n Ọ̀gbọ́n Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà ni aṣáájú àwọn ìwàrẹ̀fà náà. a rí àwọn olóyè bí Ọbaálá, Rísàwẹ́, Ọ̀dọlé, Léjòfi Sàlórò Àrápatẹ́ àti Ọbádò ni Ìjẹ̀bú-Jèṣà bí wọ́n ti wà ni Iléṣà. |
10 |
25 |
Àdánidá je gbogbo ohun patapata to wa ni ile aye, gbogbo isele (ojo, ara, ooru a.bb.lo), gbogbo ohun elemi ati gbogbo eyi ti ko lemi. |
11 |
20 |
Agbegbe Aladawa Tibet (Tibet Autonomous Region, TAR), bakanna bi Xizang Autonomous Region ( ; Wylie: Bod-rang-skyong-ljongs; je igberikoijoba ti agbegbe aladawa ti orile-ede Saina (PRC) to je didasile ni 1965. |
12 |
2 |
Ìgbà gbogbo ni àwọn babaláwo máa gbé ẹbọọ lọ si ibẹ́, nwọn a máa bu epo lé yangí náà lórí, a máa rin sún nígbà gbogbo. |
13 |
3 |
Bí ibùdó àwọn àtọmọdọ́mọ Olúbákin ti ń gbọ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀ sí i, wọ́n yàn láti fi òpin sí ìjọba alájùmọ̀ṣe tí Olùbákin dá sílẹ̀ pẹ̀lú Olúgbo, wọ́n kórajọ sí Òbe-ńlá, wọ́n sì sọ ibẹ̀ di ibùdo Olúbo gẹ́gẹ́ bí i ọba aládé. |
14 |
3 |
Ijoba SADR gba pe awon agbegbe to wa labe ijoba orile-ede Moroko je "Agbegbe Idurolelori (Occupied Territory) " nigbati Moroko gba pe agbegbe kekere to wa labe SADR je "Aaye Idasi (Buffer Zone)." |
15 |
1 |
Ede agbegbe ni ede to je siso ni agbegbe orile-ede orileijoba kan, boya o agbegbe kekere, boya apapo ipinle tabi igberiko, tabi nibi totobi ju bayi lo. |